19/05/2026
Bo Se Nlo Leto, Eba Wa Dasi !
Ekaro o eyin ololufe wa, aajirebi? aku ojumo, aku ojumomo.
Nje nijelo, mo ba wa soro lori akole kan ti mo pe ni aale yiyan. Inu mi dun gidi gan, nitori didasi ti eyin ololufe mi ba mi dasii, ti eo da eto o'un da emi nikan.
Awuyewuye orisirisi lo jeyo nipa eto oun, alaye waye nipa siso oun ti aale yiyan je, okunfa alee yiyan ni ona kan si omiran, ari mu jade pe ASA ti ko dara ni, nseni ko ni anfaani kan rara, sugbon nse ni oje timutimu tio kan ko egbin dasinu lasan.
Okun fun ewu, ipalara, ijamba ati iku aitojo, awon Baba wa moni moni bo, won ni "bi enia ba n yan ale, bio seku pa ara re, yio seku pa Oko tabi pa aya re". Hummm, e je a be olohun oba ki eledua ma ma je ki oun ti a nje o seku pa wa oo (Amin ase).
Ewo eyin enia mi; loni ni koni dola, ti n o mu idi gan ti a fi mu oro nla yi de ori afefe.
Sugbon ni bayi, mo fe re dafun tolo, mo npada bo.
Amo kin to de, mo fe ki e like👍, comment✍️, share↪️,e tun le repost 🔄 ati pe ke ma gbagbe lati ma follow🧑🤝🧑 emi omo yin Oluwafunmilayo Omolabake Ogunsanya, ki abalayi le ma tesiwaju si.
Eseu pupo.
゚viralシfypシ゚